No products in the cart.

HERE IS THE 5th EDITION OF YORUBA NEWS FROM CELESTIAL HONOURS TELEVISION

KOKO INU IROYIN
. Ijo ccc ti sun irin ajo lilo si Ile mimo Israeli siwaju .
. Eka gbogbo ijo ccc ti owa ni orile ede United Kingdom se esin idupe opin odun.
- Ijo ccc pillar of convenant cathedral se ayeye ikore agba ti won pe akole re ni harvest of divine elevation.
- ijo central cathedral ni ilu Abuja se aseyori lori ayeye ajodun ikore won to waye ni ojo die seyin.
- gbaju gbaja osere ori itage kan keko gboye.
- orile ede Israel Pelu egbe omo Ologun Hezbolah ti orile ede Lebanon ti fi Enu Ko lori sinsinmi ogun ti eleyinbo npe ni ceasefire.
- Agbabolu lewandowski darapo mo agba Bolu Messi ati Ronaldo ninu Iwe itan UCL.